-
Sáàmù 18:àkọléBíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Sí olùdarí. Látọ̀dọ̀ Dáfídì ìránṣẹ́ Jèhófà, tí ó kọ ọ̀rọ̀ yìí lórin sí Jèhófà ní ọjọ́ tí Jèhófà gbà á lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀ àti lọ́wọ́ Sọ́ọ̀lù. Ó sọ pé:+
-