Diutarónómì 33:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó sọ pé: “Jèhófà wá láti Sínáì,+Ó sì tàn sórí wọn láti Séírì. Ògo rẹ̀ tàn láti agbègbè olókè Páránì,+Ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn ẹni mímọ́+ sì wà pẹ̀lú rẹ̀,Àwọn jagunjagun+ rẹ̀ wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀.
2 Ó sọ pé: “Jèhófà wá láti Sínáì,+Ó sì tàn sórí wọn láti Séírì. Ògo rẹ̀ tàn láti agbègbè olókè Páránì,+Ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn ẹni mímọ́+ sì wà pẹ̀lú rẹ̀,Àwọn jagunjagun+ rẹ̀ wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀.