Àwọn Onídàájọ́ 3:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Lẹ́yìn Éhúdù ni Ṣámúgárì+ ọmọ Ánátì, tó fi ọ̀pá tí wọ́n fi ń da màlúù+ pa ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ọkùnrin Filísínì;+ òun náà gba Ísírẹ́lì sílẹ̀.
31 Lẹ́yìn Éhúdù ni Ṣámúgárì+ ọmọ Ánátì, tó fi ọ̀pá tí wọ́n fi ń da màlúù+ pa ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ọkùnrin Filísínì;+ òun náà gba Ísírẹ́lì sílẹ̀.