Àwọn Onídàájọ́ 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó ránṣẹ́ sí Bárákì+ ọmọ Ábínóámù láti Kedeṣi-náfútálì,+ ó sì sọ fún un pé: “Ṣebí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ti pàṣẹ? ‘Lọ sí* Òkè Tábórì, kí o sì kó ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ọkùnrin dání látinú àwọn ọmọ Náfútálì àti Sébúlúnì.
6 Ó ránṣẹ́ sí Bárákì+ ọmọ Ábínóámù láti Kedeṣi-náfútálì,+ ó sì sọ fún un pé: “Ṣebí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ti pàṣẹ? ‘Lọ sí* Òkè Tábórì, kí o sì kó ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ọkùnrin dání látinú àwọn ọmọ Náfútálì àti Sébúlúnì.