ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 4:21, 22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Àmọ́ Jáẹ́lì ìyàwó Hébà mú èèkàn àgọ́, ó sì mú òòlù dání. Nígbà tí ọkùnrin náà ti sùn lọ fọnfọn, tó sì ti rẹ̀ ẹ́, Jáẹ́lì yọ́ lọ sọ́dọ̀ rẹ̀, ó gbá èèkàn àgọ́ náà wọnú ẹ̀bátí rẹ̀, ó gbá a wọlẹ̀, ọkùnrin náà sì kú.+

      22 Bárákì wá Sísérà débẹ̀, Jáẹ́lì sì jáde wá pàdé rẹ̀, ó sọ fún un pé: “Máa bọ̀, jẹ́ kí n fi ọkùnrin tí ò ń wá hàn ọ́.” Bárákì bá tẹ̀ lé e wọlé, ó sì rí òkú Sísérà nílẹ̀, pẹ̀lú èèkàn àgọ́ tí Jáẹ́lì gbá wọnú ẹ̀bátí rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́