Àwọn Onídàájọ́ 6:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Mídíánì wá ń jọba lé Ísírẹ́lì lórí.+ Torí Mídíánì, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe àwọn ibi tí wọ́n lè sá pa mọ́ sí* nínú àwọn òkè, nínú àwọn ihò àti láwọn ibi tó ṣòroó dé.+
2 Mídíánì wá ń jọba lé Ísírẹ́lì lórí.+ Torí Mídíánì, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe àwọn ibi tí wọ́n lè sá pa mọ́ sí* nínú àwọn òkè, nínú àwọn ihò àti láwọn ibi tó ṣòroó dé.+