Dáníẹ́lì 10:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Lẹ́yìn náà, ó sọ pé: “Má bẹ̀rù,+ ìwọ ọkùnrin tó ṣeyebíye gan-an.*+ Kí o ní àlàáfíà.+ Jẹ́ alágbára, àní kí o jẹ́ alágbára.” Bó ṣe ń bá mi sọ̀rọ̀, mo lókun, mo sì sọ pé: “Kí olúwa mi sọ̀rọ̀, torí o ti fún mi lókun.”
19 Lẹ́yìn náà, ó sọ pé: “Má bẹ̀rù,+ ìwọ ọkùnrin tó ṣeyebíye gan-an.*+ Kí o ní àlàáfíà.+ Jẹ́ alágbára, àní kí o jẹ́ alágbára.” Bó ṣe ń bá mi sọ̀rọ̀, mo lókun, mo sì sọ pé: “Kí olúwa mi sọ̀rọ̀, torí o ti fún mi lókun.”