Jóṣúà 19:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kèké kejì+ wá mú Síméónì, ẹ̀yà Síméónì+ ní ìdílé-ìdílé. Ogún wọn sì wà láàárín ogún Júdà.+ Jóṣúà 19:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Élítóládì,+ Bẹ́túlì, Hóómà,