Àwọn Onídàájọ́ 3:26, 27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ní gbogbo ìgbà tí wọ́n fi ń dúró, Éhúdù ti sá lọ, ó kọjá ibi àwọn ère gbígbẹ́,*+ ó sì dé Séírà láìséwu. 27 Nígbà tó débẹ̀, ó fun ìwo+ ní agbègbè olókè Éfúrémù;+ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì sọ̀ kalẹ̀ kúrò ní agbègbè olókè náà, òun ló ṣáájú wọn.
26 Ní gbogbo ìgbà tí wọ́n fi ń dúró, Éhúdù ti sá lọ, ó kọjá ibi àwọn ère gbígbẹ́,*+ ó sì dé Séírà láìséwu. 27 Nígbà tó débẹ̀, ó fun ìwo+ ní agbègbè olókè Éfúrémù;+ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì sọ̀ kalẹ̀ kúrò ní agbègbè olókè náà, òun ló ṣáájú wọn.