Àwọn Onídàájọ́ 14:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ẹ̀mí Jèhófà wá fún un lágbára,+ ó sì lọ sí Áṣíkẹ́lónì,+ ó ṣá ọgbọ̀n (30) nínú àwọn ọkùnrin wọn balẹ̀, ó sì bọ́ aṣọ wọn, ó wá kó àwọn aṣọ náà fún àwọn tó já àlọ́ náà.+ Inú ń bí i gidigidi bó ṣe ń gòkè pa dà lọ sí ilé bàbá rẹ̀.
19 Ẹ̀mí Jèhófà wá fún un lágbára,+ ó sì lọ sí Áṣíkẹ́lónì,+ ó ṣá ọgbọ̀n (30) nínú àwọn ọkùnrin wọn balẹ̀, ó sì bọ́ aṣọ wọn, ó wá kó àwọn aṣọ náà fún àwọn tó já àlọ́ náà.+ Inú ń bí i gidigidi bó ṣe ń gòkè pa dà lọ sí ilé bàbá rẹ̀.