-
Àwọn Onídàájọ́ 7:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Jèhófà wá sọ fún Gídíónì pé: “Ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300) ọkùnrin tó lá omi ni màá fi gbà yín là, mo sì máa fi Mídíánì lé ọ lọ́wọ́.+ Jẹ́ kí gbogbo àwọn yòókù pa dà sílé.”
-