-
Àwọn Onídàájọ́ 7:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Tẹ́tí sí ohun tí wọ́n ń sọ, lẹ́yìn náà, wàá ní ìgboyà* láti gbógun ja ibùdó náà.” Torí náà, òun àti Púrà ìránṣẹ́ rẹ̀ lọ sí etí ibi tí àwọn ọmọ ogun náà pàgọ́ sí.
-