-
Àwọn Onídàájọ́ 7:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Torí náà, lẹ́yìn tí wọ́n gba oúnjẹ àtàwọn ìwo lọ́wọ́ àwọn èèyàn náà, ó ní kí gbogbo ọkùnrin Ísírẹ́lì yòókù pa dà sílé, àwọn ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300) ọkùnrin náà nìkan ló sì ní kó dúró. Ibùdó Mídíánì wà nísàlẹ̀ rẹ̀ ní pẹ̀tẹ́lẹ̀.+
-