ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 14:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Ó ń mú kí àgbá kẹ̀kẹ́ yọ kúrò lára àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin wọn, ìyẹn sì ń mú kó nira fún wọn láti wa àwọn kẹ̀kẹ́ náà, àwọn ará Íjíbítì sì ń sọ pé: “Ẹ má ṣe jẹ́ ká fọwọ́ kan Ísírẹ́lì rárá o, torí Jèhófà ń gbèjà wọn, ó sì ń bá àwa ọmọ Íjíbítì jà.”+

  • 2 Àwọn Ọba 7:6, 7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Jèhófà ti mú kí ibùdó àwọn ará Síríà gbọ́ ìró àwọn kẹ̀kẹ́ ogun, ìró àwọn ẹṣin àti ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ ogun.+ Torí náà, wọ́n sọ fún ara wọn pé: “Ẹ wò ó! Ọba Ísírẹ́lì ti háyà àwọn ọba àwọn ọmọ Hétì àti àwọn ọba Íjíbítì láti wá gbéjà kò wá!” 7 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, wọ́n dìde, wọ́n sì sá lọ nígbà tí ilẹ̀ ti ṣú, wọ́n fi àwọn àgọ́ wọn àti àwọn ẹṣin wọn àti àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọn sílẹ̀, gbogbo ibùdó náà wà bó ṣe wà, wọ́n sì sá lọ nítorí ẹ̀mí* wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́