-
Àwọn Onídàájọ́ 8:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ó wá kúrò níbẹ̀ lọ sí Pénúélì, ó sì béèrè ohun kan náà lọ́wọ́ wọn, àmọ́ èsì tí àwọn ọkùnrin Súkótù fún un gẹ́lẹ́ ni àwọn ọkùnrin Pénúélì fún un. 9 Ló bá tún sọ fún àwọn ọkùnrin Pénúélì náà pé: “Tí mo bá pa dà ní àlàáfíà, màá wó ilé gogoro+ yìí.”
-