Jóṣúà 14:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀yà méjì ni wọ́n ka àwọn àtọmọdọ́mọ Jósẹ́fù sí,+ ìyẹn Mánásè àti Éfúrémù;+ wọn ò pín lára ilẹ̀ náà fún àwọn ọmọ Léfì, àfi àwọn ìlú+ tí wọ́n á máa gbé àti ibi tí àwọn ẹran ọ̀sìn wọn á ti máa jẹko, tí ohun ìní wọn sì máa wà.+
4 Ẹ̀yà méjì ni wọ́n ka àwọn àtọmọdọ́mọ Jósẹ́fù sí,+ ìyẹn Mánásè àti Éfúrémù;+ wọn ò pín lára ilẹ̀ náà fún àwọn ọmọ Léfì, àfi àwọn ìlú+ tí wọ́n á máa gbé àti ibi tí àwọn ẹran ọ̀sìn wọn á ti máa jẹko, tí ohun ìní wọn sì máa wà.+