-
Àwọn Onídàájọ́ 9:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nígbà tí wọ́n sọ fún Jótámù, ojú ẹsẹ̀ ló lọ dúró sórí Òkè Gérísímù,+ ó gbé ohùn rẹ̀ sókè, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ fetí sí mi, ẹ̀yin olórí Ṣékémù kí Ọlọ́run lè fetí sí yín.
-