ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 16:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Àwọn alákòóso Filísínì kóra jọ láti rú ẹbọ ńlá sí Dágónì+ ọlọ́run wọn, kí wọ́n sì ṣe àjọyọ̀, torí wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run wa ti fi Sámúsìn ọ̀tá wa lé wa lọ́wọ́!”

  • 1 Sámúẹ́lì 5:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Nígbà tí wọ́n dìde ní àárọ̀ kùtù ọjọ́ tó tẹ̀ lé e, Dágónì tún ti ṣubú, ó sì dojú bolẹ̀ níwájú Àpótí Jèhófà. Orí Dágónì àti àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀ méjèèjì tí gé kúrò, wọ́n sì wà ní ibi àbáwọlé. Ibi tó dà bí ẹja lára rẹ̀ nìkan* ló ṣẹ́ kù.

  • 2 Àwọn Ọba 1:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Nígbà náà, Ahasáyà já bọ́ láti ibi asẹ́ tó wà ní yàrá òrùlé rẹ̀ ní Samáríà, ó sì fara pa. Torí náà, ó rán àwọn òjíṣẹ́, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ lọ wádìí lọ́dọ̀ Baali-sébúbù ọlọ́run Ẹ́kírónì+ bóyá ibi tí mo fi ṣèṣe yìí máa san.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́