1 Àwọn Ọba 18:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Lọ́wọ́ ọ̀sán, Èlíjà bẹ̀rẹ̀ sí í fi wọ́n ṣe yẹ̀yẹ́ pé: “Ẹ fi gbogbo ohùn yín pè é! Ṣebí ọlọ́run ni!+ Bóyá ó ti ronú lọ tàbí kó jẹ́ pé ó ti lọ yàgbẹ́.* Ó sì lè jẹ́ pé ńṣe ló sùn lọ, tó sì yẹ kí ẹnì kan jí i!”
27 Lọ́wọ́ ọ̀sán, Èlíjà bẹ̀rẹ̀ sí í fi wọ́n ṣe yẹ̀yẹ́ pé: “Ẹ fi gbogbo ohùn yín pè é! Ṣebí ọlọ́run ni!+ Bóyá ó ti ronú lọ tàbí kó jẹ́ pé ó ti lọ yàgbẹ́.* Ó sì lè jẹ́ pé ńṣe ló sùn lọ, tó sì yẹ kí ẹnì kan jí i!”