-
Àwọn Onídàájọ́ 11:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Àmọ́, ìyàwó Gílíádì náà bí àwọn ọmọkùnrin fún un. Nígbà tí àwọn ọmọ ìyàwó rẹ̀ dàgbà, wọ́n lé Jẹ́fútà jáde, wọ́n sì sọ fún un pé: “O ò ní bá wa pín ogún kankan ní agbo ilé bàbá wa, torí ọmọ obìnrin míì ni ọ́.”
-