-
Jóṣúà 21:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe fi kèké pín àwọn ìlú yìí àtàwọn ibi ìjẹko wọn fún àwọn ọmọ Léfì nìyẹn, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.+
-
-
Jóṣúà 21:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Látinú ìpín ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè: Táánákì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Gati-rímónì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, ó jẹ́ ìlú méjì.
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 5:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Wọn ò kó+ fàdákà kankan lójú ogun.
-