-
Àwọn Onídàájọ́ 10:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Nígbà tó yá, a pe àwọn ọmọ Ámónì+ jọ, wọ́n sì pàgọ́ sí Gílíádì. Torí náà àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kóra jọ, wọ́n sì pàgọ́ sí Mísípà.
-