Àwọn Onídàájọ́ 11:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ẹ̀mí Jèhófà wá bà lé Jẹ́fútà,+ ó sì gba Gílíádì àti Mánásè kọjá lọ sí Mísípè ti Gílíádì,+ láti Mísípè ti Gílíádì ó lọ sọ́dọ̀ àwọn ọmọ Ámónì.
29 Ẹ̀mí Jèhófà wá bà lé Jẹ́fútà,+ ó sì gba Gílíádì àti Mánásè kọjá lọ sí Mísípè ti Gílíádì,+ láti Mísípè ti Gílíádì ó lọ sọ́dọ̀ àwọn ọmọ Ámónì.