10 Àmọ́ wọn ò lé àwọn ọmọ Kénáánì tó ń gbé ní Gésérì+ kúrò, àwọn ọmọ Kénáánì ṣì ń gbé láàárín Éfúrémù títí di òní yìí,+ wọ́n sì ń fipá kó wọn ṣiṣẹ́ àṣekára.+
16 (Fáráò ọba Íjíbítì ti wá gba Gésérì, ó dáná sun ún, ó sì pa àwọn ọmọ Kénáánì+ tó ń gbé ìlú náà. Nítorí náà, ó fi ṣe ẹ̀bùn ìdágbére* fún ọmọbìnrin rẹ̀,+ aya Sólómọ́nì.)