-
Jóṣúà 13:1-3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ní báyìí, Jóṣúà ti darúgbó, ó sì ti lọ́jọ́ lórí.+ Jèhófà sọ fún un pé: “O ti darúgbó, o sì ti lọ́jọ́ lórí; àmọ́ ẹ ò tíì gba* èyí tó pọ̀ jù nínú ilẹ̀ náà. 2 Àwọn ilẹ̀ tó ṣẹ́ kù nìyí:+ gbogbo ilẹ̀ àwọn Filísínì àti ti gbogbo àwọn ará Géṣúrì+ 3 (láti ẹ̀ka odò Náílì* tó wà ní ìlà oòrùn* Íjíbítì títí dé ààlà Ẹ́kírónì lọ sí àríwá, tí wọ́n máa ń pè ní ilẹ̀ àwọn ọmọ Kénáánì)+ pẹ̀lú ilẹ̀ àwọn alákòóso Filísínì márààrún,+ ìyẹn àwọn ará Gásà, àwọn ará Áṣídódì,+ àwọn ará Áṣíkẹ́lónì,+ àwọn ará Gátì+ àti àwọn ará Ẹ́kírónì;+ ilẹ̀ àwọn Áfímù+
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 10:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Jèhófà wá bínú gidigidi sí Ísírẹ́lì, ó sì fi wọ́n lé àwọn Filísínì àtàwọn ọmọ Ámónì lọ́wọ́.+
-