-
Àwọn Onídàájọ́ 13:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Àmọ́ áńgẹ́lì Jèhófà sọ fún Mánóà pé: “Tí mo bá dúró, mi ò ní jẹ oúnjẹ rẹ; àmọ́ tó bá wù ọ́ láti rú ẹbọ sísun sí Jèhófà, o lè rú u.” Mánóà ò mọ̀ pé áńgẹ́lì Jèhófà ni.
-