-
Jóṣúà 19:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Ààlà náà sì pa dà sí Rámà títí dé Tírè+ tó jẹ́ ìlú olódi. Ó wá pa dà sí Hósà, ó sì parí sí òkun, ní agbègbè Ákísíbù,
-
-
Jóṣúà 19:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Èyí ni ogún ẹ̀yà Áṣérì ní ìdílé-ìdílé.+ Èyí sì ni àwọn ìlú náà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-