Àwọn Onídàájọ́ 16:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọ́n wá lọ lúgọ sí yàrá inú, ó sì ké jáde pé: “Sámúsìn, àwọn Filísínì ti wá mú ọ!” Ló bá já àwọn okùn náà, bí òwú ọ̀gbọ̀* ṣe máa ń tètè já tí iná bá kàn án.+ Wọn ò mọ àṣírí agbára rẹ̀.
9 Wọ́n wá lọ lúgọ sí yàrá inú, ó sì ké jáde pé: “Sámúsìn, àwọn Filísínì ti wá mú ọ!” Ló bá já àwọn okùn náà, bí òwú ọ̀gbọ̀* ṣe máa ń tètè já tí iná bá kàn án.+ Wọn ò mọ àṣírí agbára rẹ̀.