-
Àwọn Onídàájọ́ 15:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Torí náà, Sámúsìn lọ mú ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300) kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀. Ó wá mú àwọn ògùṣọ̀, ó so ìrù àwọn kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ náà mọ́ra, ó sì fi ògùṣọ̀ kan sáàárín ìrù méjì. 5 Ó wá fi iná sí àwọn ògùṣọ̀ náà, ó sì rán àwọn kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ náà lọ sínú oko ọkà àwọn Filísínì. Gbogbo ohun tó wà níbẹ̀ ló dáná sun, látorí ìtí ọkà dórí ọkà tó wà ní òró, títí kan àwọn ọgbà àjàrà àti àwọn igi ólífì.
-