-
Àwọn Onídàájọ́ 13:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Mánóà bẹ Jèhófà, ó sì sọ pé: “Jọ̀ọ́, Jèhófà. Jẹ́ kí èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ tí o ṣẹ̀ṣẹ̀ rán wá tún pa dà wá, kó sọ fún wa ohun tí a máa ṣe nípa ọmọ tí a máa bí.”
-