-
Àwọn Onídàájọ́ 2:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Torí náà, Jèhófà máa ń yan àwọn onídàájọ́ tó máa gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tó ń kó wọn lẹ́rù.+
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 15:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ogún (20) ọdún+ ló fi jẹ́ onídàájọ́ ní Ísírẹ́lì nígbà ayé àwọn Filísínì.
-