-
Àwọn Onídàájọ́ 18:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Àwọn ọkùnrin márùn-ún náà wá ń bá ìrìn àjò wọn lọ, wọ́n sì dé Láíṣì.+ Wọ́n rí bí àwọn tó ń gbé ibẹ̀ kò ṣe gbára lé ẹnikẹ́ni bíi ti àwọn ọmọ Sídónì. Èèyàn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ ni wọ́n, wọn kì í fura,+ kò sì sí aninilára kankan tó wá jẹ gàba lé wọn lórí ní ilẹ̀ náà láti yọ wọ́n lẹ́nu. Wọ́n jìnnà gan-an sí àwọn ọmọ Sídónì, wọn kò sì bá àwọn míì da nǹkan pọ̀.
-