Àwọn Onídàájọ́ 19:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Nígbà yẹn, tí kò sí ọba ní Ísírẹ́lì,+ ọmọ Léfì kan tó ń gbé apá ibi tó jìnnà ní agbègbè olókè Éfúrémù+ lákòókò yẹn fẹ́ wáhàrì* kan láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù+ ní Júdà.
19 Nígbà yẹn, tí kò sí ọba ní Ísírẹ́lì,+ ọmọ Léfì kan tó ń gbé apá ibi tó jìnnà ní agbègbè olókè Éfúrémù+ lákòókò yẹn fẹ́ wáhàrì* kan láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù+ ní Júdà.