Àwọn Onídàájọ́ 20:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣẹ́rí pa dà lójú ogun, àwọn ọkùnrin Bẹ́ńjámínì bẹ̀rẹ̀ sí í gbógun jà wọ́n, wọ́n sì pa nǹkan bí ọgbọ̀n (30) ọkùnrin Ísírẹ́lì,+ wọ́n wá sọ pé: “Ó dájú pé a tún ti ń ṣẹ́gun wọn bíi ti tẹ́lẹ̀.”+
39 Nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣẹ́rí pa dà lójú ogun, àwọn ọkùnrin Bẹ́ńjámínì bẹ̀rẹ̀ sí í gbógun jà wọ́n, wọ́n sì pa nǹkan bí ọgbọ̀n (30) ọkùnrin Ísírẹ́lì,+ wọ́n wá sọ pé: “Ó dájú pé a tún ti ń ṣẹ́gun wọn bíi ti tẹ́lẹ̀.”+