-
Àwọn Onídàájọ́ 20:48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì yíjú pa dà, wọ́n sì gbógun ja àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì, wọ́n fi idà pa àwọn tó wà nínú ìlú, látorí èèyàn dórí ẹran ọ̀sìn, gbogbo ohun tó ṣẹ́ kù. Bákan náà, gbogbo ìlú tí wọ́n rí lójú ọ̀nà ni wọ́n dáná sun.
-