Àwọn Onídàájọ́ 1:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nígbà tí Ísírẹ́lì lágbára sí i, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í fipá kó àwọn ọmọ Kénáánì ṣiṣẹ́ àṣekára,+ àmọ́ wọn ò lé wọn kúrò pátápátá.+
28 Nígbà tí Ísírẹ́lì lágbára sí i, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í fipá kó àwọn ọmọ Kénáánì ṣiṣẹ́ àṣekára,+ àmọ́ wọn ò lé wọn kúrò pátápátá.+