-
Jóṣúà 23:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ẹ̀yin fúnra yín ti rí gbogbo ohun tí Jèhófà Ọlọ́run yín ṣe sí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè yìí nítorí yín, torí pé Jèhófà Ọlọ́run yín ló ń jà fún yín.+
-
-
Jóṣúà 24:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Ísírẹ́lì ṣì ń sin Jèhófà ní gbogbo ọjọ́ ayé Jóṣúà àti ní gbogbo ọjọ́ ayé àwọn àgbààgbà tí wọ́n ṣẹ́ kù lẹ́yìn tí Jóṣúà kú, tí wọ́n sì ti mọ gbogbo ohun tí Jèhófà ṣe nítorí Ísírẹ́lì.+
-