Rúùtù 2:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Torí náà, ó wà lọ́dọ̀ àwọn òṣìṣẹ́ Bóásì, ó ń pèéṣẹ́ títí ìkórè ọkà bálì+ àti àlìkámà* fi parí. Ọ̀dọ̀ ìyá ọkọ rẹ̀ ló sì ń gbé.+
23 Torí náà, ó wà lọ́dọ̀ àwọn òṣìṣẹ́ Bóásì, ó ń pèéṣẹ́ títí ìkórè ọkà bálì+ àti àlìkámà* fi parí. Ọ̀dọ̀ ìyá ọkọ rẹ̀ ló sì ń gbé.+