Rúùtù 2:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Náómì wá sọ fún ìyàwó ọmọ rẹ̀ pé: “Ìbùkún ni fún un látọ̀dọ̀ Jèhófà, ẹni tó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí àwọn alààyè àti òkú.”+ Náómì ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ pé: “Mọ̀lẹ́bí wa ni ọkùnrin náà.+ Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùtúnrà* wa.”+
20 Náómì wá sọ fún ìyàwó ọmọ rẹ̀ pé: “Ìbùkún ni fún un látọ̀dọ̀ Jèhófà, ẹni tó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí àwọn alààyè àti òkú.”+ Náómì ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ pé: “Mọ̀lẹ́bí wa ni ọkùnrin náà.+ Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùtúnrà* wa.”+