-
Rúùtù 2:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Náómì sọ fún Rúùtù ìyàwó ọmọ rẹ̀ pé: “Ọmọ mi, ó dáa kí o wà lọ́dọ̀ àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ obìnrin ju kí o lọ sí oko ẹlòmíì tí wọ́n á ti máa dà ọ́ láàmú.”
-