Rúùtù 3:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó bi í pé: “Ta nìyí?” Ó fèsì pé: “Èmi Rúùtù ìránṣẹ́ rẹ ni. Jọ̀ọ́ fi aṣọ rẹ* bo ìránṣẹ́ rẹ, torí ìwọ jẹ́ olùtúnrà.”+
9 Ó bi í pé: “Ta nìyí?” Ó fèsì pé: “Èmi Rúùtù ìránṣẹ́ rẹ ni. Jọ̀ọ́ fi aṣọ rẹ* bo ìránṣẹ́ rẹ, torí ìwọ jẹ́ olùtúnrà.”+