Rúùtù 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Òótọ́ ni pé olùtúnrà+ ni mí, àmọ́ olùtúnrà kan wà tó bá ọ tan jù mí lọ.+