ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 1:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Lẹ́yìn náà, wọ́n dìde ní àárọ̀ kùtù, wọ́n forí balẹ̀ níwájú Jèhófà, wọ́n sì pa dà sí ilé wọn ní Rámà.+ Ẹlikénà ní ìbálòpọ̀ pẹ̀lú Hánà ìyàwó rẹ̀, Jèhófà sì ṣíjú àánú wò ó.*+

  • 1 Sámúẹ́lì 7:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Sámúẹ́lì sì ń ṣe ìdájọ́ Ísírẹ́lì ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀.+

  • 1 Sámúẹ́lì 7:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ṣùgbọ́n, ó máa ń pa dà sí Rámà,+ torí ibẹ̀ ni ilé rẹ̀ wà, ó tún máa ń ṣe ìdájọ́ Ísírẹ́lì níbẹ̀. Ó sì mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Jèhófà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́