-
1 Sámúẹ́lì 5:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nígbà tí àwọn èèyàn Áṣídódì rí ohun tó ń ṣẹlẹ̀, wọ́n sọ pé: “Ẹ má ṣe jẹ́ kí Àpótí Ọlọ́run Ísírẹ́lì máa gbé pẹ̀lú wa, nítorí pé ọwọ́ rẹ̀ ti le mọ́ àwa àti Dágónì ọlọ́run wa.”
-