-
Jóṣúà 13:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Àwọn ilẹ̀ tó ṣẹ́ kù nìyí:+ gbogbo ilẹ̀ àwọn Filísínì àti ti gbogbo àwọn ará Géṣúrì+ 3 (láti ẹ̀ka odò Náílì* tó wà ní ìlà oòrùn* Íjíbítì títí dé ààlà Ẹ́kírónì lọ sí àríwá, tí wọ́n máa ń pè ní ilẹ̀ àwọn ọmọ Kénáánì)+ pẹ̀lú ilẹ̀ àwọn alákòóso Filísínì márààrún,+ ìyẹn àwọn ará Gásà, àwọn ará Áṣídódì,+ àwọn ará Áṣíkẹ́lónì,+ àwọn ará Gátì+ àti àwọn ará Ẹ́kírónì;+ ilẹ̀ àwọn Áfímù+
-
-
1 Sámúẹ́lì 6:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Nígbà tí àwọn alákòóso Filísínì márààrún rí i, wọ́n pa dà sí Ẹ́kírónì ní ọjọ́ yẹn.
-