-
1 Sámúẹ́lì 5:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Nítorí náà, wọ́n ránṣẹ́ pe gbogbo àwọn alákòóso Filísínì jọ, wọ́n sì sọ pé: “Ẹ gbé Àpótí Ọlọ́run Ísírẹ́lì kúrò lọ́dọ̀ wa, ẹ dá a pa dà sí àyè rẹ̀, kó má bàa pa àwa àti àwọn èèyàn wa.” Nítorí ìbẹ̀rù ikú ti gba gbogbo ìlú náà kan; ọwọ́ Ọlọ́run tòótọ́ sì ti le mọ́ àwọn èèyàn ibẹ̀,+
-