-
1 Sámúẹ́lì 10:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Sámúẹ́lì wá pe àwọn èèyàn náà jọ sọ́dọ̀ Jèhófà ní Mísípà,+
-
-
2 Àwọn Ọba 25:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Nígbà tí gbogbo olórí àwọn ọmọ ogun àti àwọn ọkùnrin wọn gbọ́ pé ọba Bábílónì ti yan Gẹdaláyà, lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, wọ́n wá sọ́dọ̀ Gẹdaláyà ní Mísípà. Àwọn ni Íṣímáẹ́lì ọmọ Netanáyà, Jóhánánì ọmọ Káréà, Seráyà ọmọ Táńhúmétì ará Nétófà àti Jaasanáyà ọmọ ará Máákátì pẹ̀lú àwọn ọkùnrin wọn.+
-
-
Jeremáyà 40:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Torí náà, Jeremáyà lọ sọ́dọ̀ Gẹdaláyà ọmọ Áhíkámù ní Mísípà,+ ó sì ń gbé lọ́dọ̀ rẹ̀ ní àárín àwọn èèyàn tó ṣẹ́ kù ní ilẹ̀ náà.
-