ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 5:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Ó pe orúkọ rẹ̀ ní Nóà,*+ ó sọ pé: “Ọmọ yìí á tù wá nínú* nídìí iṣẹ́ wa àti làálàá tí a ṣe torí ilẹ̀ tí Jèhófà ti fi gégùn-ún.”+

  • Jẹ́nẹ́sísì 41:51
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 51 Jósẹ́fù sọ àkọ́bí rẹ̀ ní Mánásè,*+ torí ó sọ pé, “Ọlọ́run ti mú kí n gbàgbé gbogbo ìdààmú tó bá mi àti gbogbo ilé bàbá mi.”

  • Ẹ́kísódù 2:21, 22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Lẹ́yìn náà, Mósè gbà láti dúró lọ́dọ̀ ọkùnrin náà, ó sì fún Mósè ní Sípórà+ ọmọ rẹ̀ kó fi ṣe aya. 22 Nígbà tó yá, obìnrin náà bí ọmọkùnrin kan, Mósè sì sọ ọ́ ní Gẹ́ṣómù,*+ torí ó sọ pé, “Mo ti di àjèjì nílẹ̀ àjèjì.”+

  • Mátíù 1:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ó máa bí ọmọkùnrin kan, kí o pe orúkọ rẹ̀ ní Jésù,*+ torí ó máa gba àwọn èèyàn rẹ̀ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ wọn.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́