-
2 Àwọn Ọba 9:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Tí o bá ti dé ibẹ̀, kí o wá Jéhù+ ọmọ Jèhóṣáfátì ọmọ Nímúṣì; wọlé lọ bá a, kí o ní kó dìde kúrò láàárín àwọn arákùnrin rẹ̀, kí o sì mú un lọ sínú yàrá inú lọ́hùn-ún. 3 Kí o mú ṣágo òróró náà, kí o sì dà á sí i lórí, kí o wá sọ pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Mo fòróró yàn ọ́ ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì.”’+ Lẹ́yìn náà, ṣí ilẹ̀kùn, kí o sì tètè sá lọ.”
-