1 Sámúẹ́lì 10:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nítorí náà, wọ́n lọ láti ibẹ̀ sórí òkè, àwùjọ àwọn wòlíì kan sì pàdé rẹ̀. Lọ́gán, ẹ̀mí Ọlọ́run fún un lágbára,+ ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọ tẹ́lẹ̀+ láàárín wọn.
10 Nítorí náà, wọ́n lọ láti ibẹ̀ sórí òkè, àwùjọ àwọn wòlíì kan sì pàdé rẹ̀. Lọ́gán, ẹ̀mí Ọlọ́run fún un lágbára,+ ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọ tẹ́lẹ̀+ láàárín wọn.